Èdè Ará

Wọn ni – àwọn olóye – wọn ni
Gbogbo nkan ti o nmi lórí

ilẹ̀ yìí,
Lọ má kú.

Míì mọ b’oya àgbàlagbà lọ sọ’yen
Kí kò lè je ọmọdé. Àà ó kín f’etí s’ọmọdé. Not in these parts.

Mo fẹ́ kẹ́ mu’ra yín wá sunmọ tí tèmi
— k’ẹle mójútó ìwadi mi. O ti mọ́ọ̀ yín lára ké má gbó nkan b’ẹ́ ṣé fẹ́.

It’s not that I don’t see things your way too. Ṣùgbọ́n, nígbamiran kò kin rí bẹ́. T’óò bá fẹ́ sunmọ mi, dúró n’ítosi.

K’ẹ́ má da’ra yín nínú àwọn omi t’e bá fẹ́.
Èdè yin ó yàtọ̀ sí ‘ra wọn

nítorí bẹ́, bákanáà ni ìronu yín má ǹjẹ́.
Mó d’ọ̀rọ̀ yín pọ mọ ti tèmi

láyì jẹ́ bẹ́, kò ní kan yín láti

fojúfoda mi.